1. Kor 12:26 YCE

26 Bi ẹ̀ya kan ba si njìya, gbogbo ẹ̀ya a si jùmọ ba a jìya; tabi bi a ba mbọla fun ẹ̀ya kan, gbogbo ẹ̀ya a jùmọ ba a yọ̀.

Ka pipe ipin 1. Kor 12

Wo 1. Kor 12:26 ni o tọ