1. Kor 12:29 YCE

29 Gbogbo wọn ni iṣe aposteli bi? gbogbo wọn ni iṣe woli bi? gbogbo wọn ni iṣe olukọni bi? gbogbo wọn ni iṣe iṣẹ iyanu bi?

Ka pipe ipin 1. Kor 12

Wo 1. Kor 12:29 ni o tọ