1. Kor 13:13 YCE

13 Njẹ nisisiyi igbagbọ́, ireti, ati ifẹ mbẹ, awọn mẹta yi: ṣugbọn eyiti o tobi jù ninu wọn ni ifẹ.

Ka pipe ipin 1. Kor 13

Wo 1. Kor 13:13 ni o tọ