1. Kor 14:19 YCE

19 Ṣugbọn mo fẹ ki ng kuku fi oye mi sọ ọ̀rọ marun ni ijọ, ki ng le kọ́ awọn ẹlomiran pẹlu, jù ẹgbãrun ọ̀rọ li ède aimọ̀.

Ka pipe ipin 1. Kor 14

Wo 1. Kor 14:19 ni o tọ