1. Kor 14:2 YCE

2 Nitori ẹniti nsọ̀rọ li ède aimọ̀, kò bá enia sọ̀rọ bikoṣe Ọlọrun: nitori kò si ẹniti o gbọ; ṣugbọn nipa ti Ẹmí o nsọ ohun ijinlẹ:

Ka pipe ipin 1. Kor 14

Wo 1. Kor 14:2 ni o tọ