1. Kor 3:19 YCE

19 Nitori ọgbọ́n aiye yi wèrè ni lọdọ Ọlọrun. Nitori a ti kọ ọ pe, Ẹniti o mu awọn ọlọgbọ́n ninu arekereke wọn.

Ka pipe ipin 1. Kor 3

Wo 1. Kor 3:19 ni o tọ