1. Kor 6:1 YCE

1 ẸNIKẸNI ninu nyin, ti o ni ọ̀ran kan si ẹnikeji rẹ̀, ha gbọdọ lọ pè e li ẹjọ niwaju awọn alaiṣõtọ, ki o má si jẹ niwaju awọn enia mimọ́?

Ka pipe ipin 1. Kor 6

Wo 1. Kor 6:1 ni o tọ