18 Ẹ mã sá fun àgbere. Gbogbo ẹ̀ṣẹ ti enia ndá o wà lode ara; ṣugbọn ẹniti o nṣe àgbere nṣẹ̀ si ara on tikararẹ̀.
Ka pipe ipin 1. Kor 6
Wo 1. Kor 6:18 ni o tọ