1. Kor 7:35 YCE

35 Eyi ni mo si nwi fun ère ara nyin; kì iṣe lati dẹkun fun nyin, ṣugbọn nitori eyi ti o tọ́, ati ki ẹnyin ki o le mã sin Oluwa laisi ìyapa-ọkàn.

Ka pipe ipin 1. Kor 7

Wo 1. Kor 7:35 ni o tọ