1. Kor 9:27 YCE

27 Ṣugbọn emi npọn ara mi loju, mo si nmu u wá sabẹ itẹriba: pe lẹhin ti mo ti wasu fun awọn ẹlomiran, nitori ohunkohun, ki emi tikarami máṣe di ẹni itanù.

Ka pipe ipin 1. Kor 9

Wo 1. Kor 9:27 ni o tọ