1. Tes 1:10 YCE

10 Ati lati duro dè Ọmọ rẹ̀ lati ọrun wá, ẹniti o si ji dide kuro ninu okú, ani Jesu na, ẹniti ngbà wa kuro ninu ibinu ti mbọ̀.

Ka pipe ipin 1. Tes 1

Wo 1. Tes 1:10 ni o tọ