1. Tes 1:9 YCE

9 Nitoripe awọn tikarawọn ròhin nipa wa, irú iwọle ti awa ti ni sọdọ nyin, bi ẹnyin si ti yipada si Ọlọrun kuro ninu ère lati mã sìn Ọlọrun alãye ati otitọ;

Ka pipe ipin 1. Tes 1

Wo 1. Tes 1:9 ni o tọ