1. Tes 4:10 YCE

10 Nitõtọ ẹnyin si nṣe e si gbogbo awọn ará ti o wà ni gbogbo Makedonia: ṣugbọn awa mbẹ̀ nyin, ará, pe ki ẹnyin ki o mã pọ̀ siwaju si i;

Ka pipe ipin 1. Tes 4

Wo 1. Tes 4:10 ni o tọ