1. Tes 4:9 YCE

9 Ṣugbọn niti ifẹ awọn ará, ẹ kò tun fẹ ki ẹnikẹni kọwe si nyin: nitori a ti kọ́ ẹnyin tikaranyin lati ọdọ Ọlọrun wá lati mã fẹ ara nyin.

Ka pipe ipin 1. Tes 4

Wo 1. Tes 4:9 ni o tọ