1. Tim 3:11 YCE

11 Bẹ̃ gẹgẹ li o yẹ fun awọn obinrin lati ni iwa àgba, kì nwọn má jẹ asọrọ-ẹni-lẹhin bikoṣe alairekọja, olõtọ li ohun gbogbo.

Ka pipe ipin 1. Tim 3

Wo 1. Tim 3:11 ni o tọ