1. Tim 3:12 YCE

12 Ki awọn diakoni jẹ ọkọ obinrin kan, ki nwọn ki o káwọ awọn ọmọ wọn ati ile ara wọn daradara.

Ka pipe ipin 1. Tim 3

Wo 1. Tim 3:12 ni o tọ