1. Tim 4:10 YCE

10 Nitori fun eyi li awa nṣe lãlã ti a si njijakadi, nitori awa ni ireti ninu Ọlọrun alãye, ẹniti iṣe Olugbala gbogbo enia, pẹlupẹlu ti awọn ti o gbagbọ́.

Ka pipe ipin 1. Tim 4

Wo 1. Tim 4:10 ni o tọ