1. Tim 4:3 YCE

3 Awọn ti nda-ni-lẹkun ati gbeyawo, ti nwọn si npaṣẹ lati ka ẽwọ onjẹ ti Ọlọrun ti da fun itẹwọgba pẹlu ọpẹ awọn onigbagbọ ati awọn ti o mọ otitọ.

Ka pipe ipin 1. Tim 4

Wo 1. Tim 4:3 ni o tọ