1. Tim 4:4 YCE

4 Nitori gbogbo ohun ti Ọlọrun dá li o dara, kò si ọkan ti o yẹ ki a kọ̀, bi a ba fi ọpẹ́ gbà a.

Ka pipe ipin 1. Tim 4

Wo 1. Tim 4:4 ni o tọ