Mak 12:38 YCE

38 O si wi fun wọn ninu ẹkọ́ rẹ̀ pe, Ẹ mã kiyesara lọdọ awọn akọwe, ti nwọn fẹ lati mã rìn li aṣọ gigùn, ti nwọn si fẹ ikíni li ọjà,

Ka pipe ipin Mak 12

Wo Mak 12:38 ni o tọ