Mak 12:44 YCE

44 Nitori gbogbo nwọn sọ sinu rẹ̀ ninu ọ̀pọlọpọ ini wọn; ṣugbọn on ninu aini rẹ̀ o sọ ohun gbogbo ti o ni si i, ani gbogbo ini rẹ̀.

Ka pipe ipin Mak 12

Wo Mak 12:44 ni o tọ