Mak 13:22 YCE

22 Nitori awọn eke Kristi, ati awọn eke woli yio dide, nwọn o si fi àmi ati ohun iyanu hàn, tobẹ̃ bi o ṣe iṣe, nwọn iba tàn awọn ayanfẹ pãpã.

Ka pipe ipin Mak 13

Wo Mak 13:22 ni o tọ