Mak 13:28 YCE

28 Nisisiyi ẹ kọ́ owe lara igi ọpọtọ; Nigbati ẹ̀ka rẹ̀ ba yọ titun, ti o ba si ru ewé, ẹnyin mọ̀ pe igba ẹ̃rùn sunmọ etile:

Ka pipe ipin Mak 13

Wo Mak 13:28 ni o tọ