Mak 14:1 YCE

1 LẸHIN ọjọ meji ni ajọ irekọja, ati ti aiwukara: ati awọn olori alufa ati awọn akọwe nwá ọ̀na bi nwọn iba ti fi ẹ̀tan mu u, ki nwọn ki o pa a.

Ka pipe ipin Mak 14

Wo Mak 14:1 ni o tọ