Mak 14:13 YCE

13 O si rán awọn meji ninu awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀, o si wi fun wọn pe, Ẹ lọ si ilu, ọkunrin kan ti nrù ìṣa omi yio pade nyin: ẹ mã tọ̀ ọ lẹhin.

Ka pipe ipin Mak 14

Wo Mak 14:13 ni o tọ