Mak 14:16 YCE

16 Awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ si jade lọ, nwọn wá si ilu, nwọn si ri i gẹgẹ bi o ti sọ fun wọn: nwọn si pèse irekọja silẹ.

Ka pipe ipin Mak 14

Wo Mak 14:16 ni o tọ