Mak 14:18 YCE

18 Bi nwọn si ti joko ti nwọn njẹun, Jesu wipe, Lõtọ ni mo wi fun nyin, Ọkan ninu nyin yio fi mi hàn, ani on na ti mba mi jẹun.

Ka pipe ipin Mak 14

Wo Mak 14:18 ni o tọ