Mak 14:26 YCE

26 Nigbati nwọn si kọ orin kan tan, nwọn jade lọ sori òke Olifi.

Ka pipe ipin Mak 14

Wo Mak 14:26 ni o tọ