Mak 14:37 YCE

37 O si wá, o ba wọn, nwọn nsùn, o si wi fun Peteru pe, Simoni, iwọ nsùn? iwọ kò le ṣọna ni wakati kan?

Ka pipe ipin Mak 14

Wo Mak 14:37 ni o tọ