Mak 14:41 YCE

41 O si wá li ẹrinkẹta, o si wi fun wọn pe, Ẹ mã sùn wayi, ki ẹ si mã simi: o to bẹ̃, wakati na de; wo o, a fi Ọmọ-enia le awọn ẹlẹṣẹ lọwọ.

Ka pipe ipin Mak 14

Wo Mak 14:41 ni o tọ