Mak 14:53 YCE

53 Nwọn si mu Jesu lọ ṣọdọ olori alufa: gbogbo awọn olori alufa, ati awọn agbagba, ati awọn akọwe si pejọ pẹlu rẹ̀.

Ka pipe ipin Mak 14

Wo Mak 14:53 ni o tọ