Mak 14:70 YCE

70 O si tún sẹ́. O si pẹ diẹ, awọn ti o duro nibẹ̀ tún wi fun Peteru pe, Lõtọ ni, ọkan ninu wọn ni iwọ iṣe: nitoripe ara Galili ni iwọ, ède rẹ si jọ bẹ̃.

Ka pipe ipin Mak 14

Wo Mak 14:70 ni o tọ