Mak 15:15 YCE

15 Pilatu si nfẹ se eyi ti o wù awọn enia, o da Barabba silẹ fun wọn. Nigbati o si nà Jesu tan, o fà a le wọn lọwọ lati kàn a mọ agbelebu.

Ka pipe ipin Mak 15

Wo Mak 15:15 ni o tọ