Mak 15:24 YCE

24 Nigbati nwọn si kàn a mọ agbelebu tan, nwọn si pín aṣọ rẹ̀, nwọn si ṣẹ gège lori wọn, eyi ti olukuluku iba mú.

Ka pipe ipin Mak 15

Wo Mak 15:24 ni o tọ