Mak 16:12 YCE

12 Lẹhin eyini, o si fi ara hàn fun awọn meji ninu wọn li ọna miran, bi nwọn ti nrìn li ọ̀na, ti nwọn si nlọ si igberiko.

Ka pipe ipin Mak 16

Wo Mak 16:12 ni o tọ