Mak 6:1 YCE

1 O SI jade nibẹ̀, o wá si ilu on tikararẹ̀; awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ si tọ̀ ọ lẹhin.

Ka pipe ipin Mak 6

Wo Mak 6:1 ni o tọ