Mak 6:37 YCE

37 Ṣugbọn o dahùn o si wi fun wọn pe, Ẹ fun wọn li onjẹ. Nwọn si wi fun u pe, Awa o ha lọ irà akara igba owo idẹ ki a si fifun wọn jẹ?

Ka pipe ipin Mak 6

Wo Mak 6:37 ni o tọ