Mak 7:2 YCE

2 Nigbati nwọn ri omiran ninu awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ nfi ọwọ aimọ́ jẹun, eyini ni li aiwẹ̀ ọwọ́, nwọn mba wọn wijọ.

Ka pipe ipin Mak 7

Wo Mak 7:2 ni o tọ