Mak 8:2 YCE

2 Ãnu ijọ enia nṣe mi, nitoriti o di ijọ mẹta nisisiyi ti nwọn ti wà lọdọ mi, nwọn kò si li ohun ti nwọn o jẹ:

Ka pipe ipin Mak 8

Wo Mak 8:2 ni o tọ