Mak 9:41 YCE

41 Nitori ẹnikẹni ti o ba fi ago omi fun nyin mu li orukọ mi, nitoriti ẹnyin jẹ ti Kristi, lõtọ ni mo wi fun nyin, on kì yio padanù ère rẹ̀ bi o ti wù ki o ri.

Ka pipe ipin Mak 9

Wo Mak 9:41 ni o tọ