Mak 9:50 YCE

50 Iyọ̀ dara: ṣugbọn bi iyọ̀ ba sọ agbara rẹ̀ nù, kili ẹ o fi mu u dùn? Ẹ ni iyọ̀ ninu ara nyin, ki ẹ si ma wà li alafia lãrin ara nyin.

Ka pipe ipin Mak 9

Wo Mak 9:50 ni o tọ