Rom 1:17 YCE

17 Nitori ninu rẹ̀ li ododo Ọlọrun hàn lati igbagbọ́ de igbagbọ́: gẹgẹ bi a ti kọ ọ pe, Ṣugbọn olododo yio wà nipa igbagbọ́.

Ka pipe ipin Rom 1

Wo Rom 1:17 ni o tọ