Rom 1:4 YCE

4 Ẹniti a pinnu rẹ̀ lati jẹ pẹlu agbara Ọmọ Ọlọrun, gẹgẹ bi Ẹmí iwa mimọ́, nipa ajinde kuro ninu okú, ani Jesu Kristi Oluwa wa:

Ka pipe ipin Rom 1

Wo Rom 1:4 ni o tọ