Rom 11:1 YCE

1 NJẸ mo ni, Ọlọrun ha ta awọn enia rẹ̀ nù bi? Ki a má ri. Nitori Israeli li emi pẹlu, lati inu irú-ọmọ Abrahamu, li ẹ̀ya Benjamini.

Ka pipe ipin Rom 11

Wo Rom 11:1 ni o tọ