Rom 11:18 YCE

18 Máṣe ṣe fefé si awọn ẹ̀ka na. Ṣugbọn bi iwọ ba nṣe fefé, iwọ kọ́ li o rù gbòngbo, ṣugbọn gbòngbo li o rù iwọ.

Ka pipe ipin Rom 11

Wo Rom 11:18 ni o tọ