Rom 11:23 YCE

23 Ati awọn pẹlu, bi nwọn kò ba joko sinu aigbagbọ́, a o lọ́ wọn sinu rẹ̀: nitori Ọlọrun le tún wọn lọ́ sinu rẹ̀.

Ka pipe ipin Rom 11

Wo Rom 11:23 ni o tọ