Rom 13:5 YCE

5 Nitorina ẹnyin kò gbọdọ ṣaima tẹriba, kì iṣe nitoriti ibinu nikan, ṣugbọn nitori ẹri-ọkàn pẹlu.

Ka pipe ipin Rom 13

Wo Rom 13:5 ni o tọ