Rom 14:20 YCE

20 Nitori onjẹ máṣe bi iṣẹ Ọlọrun ṣubu. Ohun gbogbo li o mọ́ nitõtọ; ṣugbọn ibi ni fun oluwarẹ̀ na ti o njẹun lọna ikọsẹ.

Ka pipe ipin Rom 14

Wo Rom 14:20 ni o tọ