Rom 14:23 YCE

23 Ṣugbọn ẹniti o ba nṣiyemeji, o jẹbi bi o ba jẹ, nitoriti kò ti inu igbagbọ́ wá: ati ohunkohun ti kò ti inu igbagbọ wá, ẹṣẹ ni.

Ka pipe ipin Rom 14

Wo Rom 14:23 ni o tọ