Rom 15:20 YCE

20 Mo du u lati mã wasu ihinrere na, kì iṣe nibiti a gbé ti da orukọ Kristi ri, ki emi ki o máṣe mọ amọle lori ipilẹ ẹlomiran.

Ka pipe ipin Rom 15

Wo Rom 15:20 ni o tọ